Gẹn 29:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si tun yún, o si bí ọmọkunrin kan; o si wipe, Nitori ti OLUWA ti gbọ́ pe a korira mi, nitorina li o ṣe fun mi li ọmọ yi pẹlu: o si sọ orukọ rẹ̀ ni Simeoni.

Gẹn 29

Gẹn 29:28-35