Gẹn 29:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lea si loyun, o si bí ọmọkunrin kan, o si sọ orukọ rẹ̀ ni Reubeni: nitori ti o wipe, OLUWA wò ìya mi nitõtọ: njẹ nitorina, ọkọ mi yio fẹ́ mi.

Gẹn 29

Gẹn 29:26-35