Gẹn 27:40 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nipa idà rẹ ni iwọ o ma gbé, iwọ o si ma sìn arakunrin rẹ; yio si ṣe nigbati iwọ ba di alagbara tan, iwọ o já àjaga rẹ̀ kuro li ọrùn rẹ.

Gẹn 27

Gẹn 27:33-46