Gẹn 27:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si sè ẹran adidùn fun mi, bi irú eyiti mo fẹ́, ki o si gbé e tọ̀ mi wá, ki emi ki o jẹ: ki ọkàn mi ki o súre fun ọ ki emi to kú.

Gẹn 27

Gẹn 27:1-10