Gẹn 27:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nisisiyi, emi bẹ̀ ọ, mu ohun ọdẹ rẹ, apó rẹ, ati ọrun rẹ, ki o si jade lọ si igbẹ́ ki o si pa ẹran-igbẹ́ fun mi wá:

Gẹn 27

Gẹn 27:1-10