Gẹn 25:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si wi fun u pe, orilẹ-ède meji ni mbẹ ninu rẹ, irú enia meji ni yio yà lati inu rẹ: awọn enia kan yio le jù ekeji lọ; ẹgbọ́n ni yio si ma sìn aburo.

Gẹn 25

Gẹn 25:13-32