Gẹn 25:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ si njàgudu ninu rẹ̀: o si wipe, bi o ba ṣe pe bẹ̃ni yio ri, ẽṣe ti mo fi ri bayi? O si lọ bère lọdọ OLUWA.

Gẹn 25

Gẹn 25:16-24