Gẹn 24:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Omidan na li ẹwà gidigidi lati wò, wundia ni, bẹ̃li ẹnikẹni kò ti imọ̀ ọ: o si sọkalẹ lọ sinu kanga, o si pọn ladugbo rẹ̀ kún, o si goke.

Gẹn 24

Gẹn 24:8-18