Gẹn 24:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, ki on to pari ọ̀rọ isọ, kiyesi i, Rebeka jade de, ẹniti a bí fun Betueli, ọmọ Milka, aya Nahori, arakunrin Abrahamu, ti on ti ladugbo rẹ̀ li ejika rẹ̀.

Gẹn 24

Gẹn 24:8-17