Gẹn 13:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Abramu ṣí agọ́ rẹ̀, o si wá o si joko ni igbo Mamre, ti o wà ni Hebroni, o si tẹ́ pẹpẹ kan nibẹ̀ fun OLUWA.

Gẹn 13

Gẹn 13:10-18