Gẹn 10:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn wọnyi li ọmọ Hamu, gẹgẹ bi idile wọn, gẹgẹ bi ohùn wọn, ni ilẹ wọn, ati li orilẹ-ède wọn.

Gẹn 10

Gẹn 10:18-25