Gẹn 10:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati àgbegbe awọn ara Kenaani ni Sidoni, bi o ti mbọ̀wa Gerari, titi de Gasa; bi o ti nlọ si Sodomu, ati Gomorra, ati Adma, ati Seboimu, titi dé Laṣa.

Gẹn 10

Gẹn 10:11-26