Est 5:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Hamani jade lọ li ọjọ na tayọ̀tayọ̀, ati pẹlu inu didùn: ṣugbọn nigbati Hamani ri Mordekai li ẹnu ọ̀na ile ọba pe, kò dide duro, bẹ̃ni kò pa ara rẹ̀ da fun on, Hamani kún fun ibinu si Mordekai.

Est 5

Est 5:1-14