Est 5:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Hamani kó ara rẹ̀ ni ijanu: nigbati o si de ile, o ranṣẹ lọ ipè awọn ọrẹ rẹ̀, ati Sereṣi aya rẹ̀.

Est 5

Est 5:1-14