Esek 5:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni yio si di ẹ̀gan ati ẹsín, ẹkọ́ ati iyanu si awọn orilẹ-ède ti o wà yi ọ ka kiri; nigbati emi o ṣe idajọ ninu rẹ ninu ibinu, ati ninu irunu on ibawi irunu. Emi Oluwa li o sọ ọ.

Esek 5

Esek 5:8-17