Esek 5:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si fi ọ ṣòfo, emi o si sọ ọ di ẹ̀gan lãrin awọn orilẹ-ède ti o yi ọ ka kiri, li oju gbogbo awọn ti nkọja.

Esek 5

Esek 5:6-17