Esek 35:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ti iwọ ti ni irira lailai, iwọ si ti fi awọn ọmọ Israeli le idà lọwọ́, li akoko idãmu wọn, li akoko ti aiṣedẽde wọn de opin.

Esek 35

Esek 35:1-9