Eks 31:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Àmi ni iṣe lãrin emi ati lãrin awọn ọmọ Israeli titilai: nitori ni ijọ́ mẹfa li OLUWA dá ọrun on aiye, ni ijọ́ keje o si simi, o si ṣe ìtura.

Eks 31

Eks 31:15-18