Eks 31:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina li awọn ọmọ Israeli yio ṣe ma pa ọjọ́ isimi mọ́, lati ma kiyesi ọjọ́ isimi lati irandiran wọn, fun majẹmu titilai.

Eks 31

Eks 31:9-18