Eks 29:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati àkara alaiwu, ati adidùn àkara alaiwu ti a fi oróro pò, ati àkara fẹlẹfẹlẹ alaiwu ti a ta oróro si lori; iyẹfun alikama ni ki o fi ṣe wọn.

Eks 29

Eks 29:1-7