Eks 29:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

EYI si li ohun ti iwọ o ṣe si wọn lati yà wọn simimọ́, lati ma ṣe alufa fun mi: mú ẹgbọ̀rọ akọmalu kan, ati àgbo meji ti kò li abùku.

Eks 29

Eks 29:1-4