Eks 25:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) OLUWA si sọ fun Mose pe, Sọ fun awọn ọmọ Israeli pe, ki nwọn ki o mú ọrẹ fun mi wá: lọwọ olukuluku enia