Eks 24:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si lọ sãrin awọsanma na, o sì gùn ori òke na: Mose si wà lori òke li ogoji ọsán ati ogoji oru.

Eks 24

Eks 24:15-18