Eks 13:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni iwọ o si yà gbogbo akọ́bi sọ̀tọ fun OLUWA, ati gbogbo akọ́bi ẹran ti iwọ ni; ti OLUWA li awọn akọ.

Eks 13

Eks 13:2-18