Eks 13:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe nigbati OLUWA ba mú ọ dé ilẹ awọn ara Kenaani, bi o ti bura fun ọ, ati fun awọn baba rẹ, ti yio si fi fun ọ.

Eks 13

Eks 13:7-20