Ẹk. Jer 4:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ani ọ̀wawa nfà ọmu jade, nwọn nfi ọmu fun awọn ọmọ wọn: ṣugbọn ọmọbinrin awọn enia mi ti di ìka, gẹgẹ bi abo ògongo li aginju.

Ẹk. Jer 4

Ẹk. Jer 4:1-12