Ẹk. Jer 2:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn nsọ fun iya wọn pe, Nibo ni ọka ati ọti-waini gbe wà? nigbati nwọn daku gẹgẹ bi awọn ti a ṣalọgbẹ ni ita ilu na, nigbati ọkàn wọn dà jade li aiya iya wọn.

Ẹk. Jer 2

Ẹk. Jer 2:11-18