Ẹk. Jer 2:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oju mi gbẹ tan fun omije, inu mi nho, a dà ẹ̀dọ mi sori ilẹ, nitori iparun ọmọbinrin awọn enia mi: nitoripe awọn ọmọ wẹ̃rẹ ati awọn ọmọ-ọmu nkulọ ni ita ilu na.

Ẹk. Jer 2

Ẹk. Jer 2:10-14