Deu 33:4-6 Yorùbá Bibeli (YCE)

4. Mose fi ofin kan lelẹ li aṣẹ fun wa, iní ti ijọ enia Jakobu.

5. O si jẹ́ ọba ni Jeṣuruni, nigbati olori awọn enia, awọn ẹ̀ya Israeli pejọ pọ̀.

6. Ki Reubeni ki o yè, ki o máṣe kú; ki enia rẹ̀ ki o máṣe mọniwọn.

Deu 33