Deu 32:52 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn iwọ o ri ilẹ na niwaju rẹ; ṣugbọn iwọ ki yio lọ sibẹ̀, si ilẹ na ti mo fi fun awọn ọmọ Israeli.

Deu 32

Deu 32:48-52