Dan 2:49 Yorùbá Bibeli (YCE)

Danieli si bère lọwọ ọba, o si fi Ṣadraki, Meṣaki, ati Abednego jẹ olori ọ̀ran igberiko Babeli; ṣugbọn Danieli joko li ẹnu-ọ̀na ãfin ọba.

Dan 2

Dan 2:43-49