Timoti Kinni 5:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Má máa mu omi nìkan, ṣugbọn máa lo waini díẹ̀, nítorí inú tí ń yọ ọ́ lẹ́nu ati nítorí àìsàn tí ó máa ń ṣe ọ́ nígbà gbogbo.

Timoti Kinni 5

Timoti Kinni 5:16-25