Timoti Kinni 5:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Má fi ìwàǹwára gbé ọwọ́ lé ẹnikẹ́ni lórí láti fi jẹ oyè ninu ìjọ, má sì di alábàápín ninu ẹ̀ṣẹ̀ ẹlòmíràn. Jẹ́ kí ọwọ́ rẹ mọ́.

Timoti Kinni 5

Timoti Kinni 5:16-25