Timoti Kinni 4:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Eniyan a máa rí anfaani níwọ̀nba tí ó bá ń ṣe eré ìdárayá ti ara, ṣugbọn anfaani ti ẹ̀mí kò lópin; nítorí ó ní anfaani ní ayé yìí, ó tún fún eniyan ní anfaani ti ayé tí ń bọ̀.

Timoti Kinni 4

Timoti Kinni 4:4-16