Timoti Kinni 4:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Má jẹ́ kí á bá ọ ní ìdí ìtàn àgbọ́sọ tí kò wúlò ati àwọn ìtànkítàn tí àwọn ìyá arúgbó fẹ́ràn. Ṣe ara rẹ yẹ fún ìgbé-ayé eniyan Ọlọrun.

Timoti Kinni 4

Timoti Kinni 4:1-9