Timoti Kinni 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí àwọn tí wọn bá ṣe iṣẹ́ diakoni dáradára ti ṣí ọ̀nà ipò gíga fún ara wọn. Wọ́n lè sọ̀rọ̀ pẹlu ọpọlọpọ ìgboyà nípa igbagbọ tí ó wà ninu Kristi Jesu.

Timoti Kinni 3

Timoti Kinni 3:12-16