Timoti Kinni 3:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Diakoni kò gbọdọ̀ ní ju aya kan lọ; ó sì gbọdọ̀ káwọ́ àwọn ọmọ rẹ̀ dáradára ati gbogbo ìdílé rẹ̀.

Timoti Kinni 3

Timoti Kinni 3:6-16