Timoti Kinni 2:6 BIBELI MIMỌ (BM)

tí ó fi ara rẹ̀ ṣe ìràpadà fún gbogbo eniyan. Èyí ni ẹ̀rí pé, Ọlọrun ṣe ètò pé kí gbogbo eniyan lè ní ìgbàlà nígbà tí àkókò rẹ̀ tó.

Timoti Kinni 2

Timoti Kinni 2:1-13