Timoti Kinni 2:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Ọlọrun kan ni ó wà, alárinà kan ni ó sì wà láàrin Ọlọrun ati eniyan; olúwarẹ̀ ni Kristi Jesu, tí òun náà jẹ́ eniyan,

Timoti Kinni 2

Timoti Kinni 2:1-15