Timoti Kinni 2:13-15 BIBELI MIMỌ (BM)

13. Nítorí Adamu ni a kọ́kọ́ dá, kí á tó dá Efa.

14. Kì í sì í ṣe Adamu ni a tàn jẹ, obinrin ni a tàn jẹ tí ó fi di ẹlẹ́ṣẹ̀.

15. Ṣugbọn a óo gba obinrin là nípa ọmọ-bíbí, bí àwọn obinrin bá dúró láì yẹsẹ̀ ninu igbagbọ ati ìfẹ́ ati ìwà mímọ́ pẹlu ìwà ìkóra-ẹni-níjàánu.

Timoti Kinni 2