Timoti Kinni 2:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn a óo gba obinrin là nípa ọmọ-bíbí, bí àwọn obinrin bá dúró láì yẹsẹ̀ ninu igbagbọ ati ìfẹ́ ati ìwà mímọ́ pẹlu ìwà ìkóra-ẹni-níjàánu.

Timoti Kinni 2

Timoti Kinni 2:13-15