Timoti Keji 4:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Luku nìkan náà ni ó kù lọ́dọ̀ mi. Mú Maku lọ́wọ́ bí o bá ń bọ̀ nítorí ó wúlò fún mi bí iranṣẹ.

Timoti Keji 4

Timoti Keji 4:1-14