Timoti Keji 4:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Demasi ti fi mí sílẹ̀ nítorí ó fẹ́ràn nǹkan ayé yìí. Ó ti lọ sí Tẹsalonika. Kirẹsẹnsi ti lọ sí Galatia. Titu ti lọ sí Dalimatia.

Timoti Keji 4

Timoti Keji 4:7-13