Timoti Keji 2:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu iṣẹ́ yìí ni mo ti ń jìyà títí mo fi di ẹlẹ́wọ̀n bí ọ̀daràn. Ṣugbọn kò sí ẹni tí ó lè fi ẹ̀wọ̀n de ọ̀rọ̀ Ọlọrun.

Timoti Keji 2

Timoti Keji 2:1-19