Timoti Keji 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, mo farada ohun gbogbo nítorí àwọn àyànfẹ́, kí àwọn náà lè rí ìgbàlà tí ó wà ninu Kristi Jesu pẹlu ògo tí ó wà títí lae.

Timoti Keji 2

Timoti Keji 2:5-14