Timoti Keji 2:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Má bá wọn lọ́wọ́ sí ọ̀rọ̀ òmùgọ̀ ati ọ̀rọ̀ òpè. Ranti pé ìjà ni wọ́n ń dá sílẹ̀.

Timoti Keji 2

Timoti Keji 2:18-24