Timoti Keji 2:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Yẹra fún àwọn ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ọ̀dọ́. Máa lépa òdodo ati ìṣòtítọ́, ìfẹ́, ati alaafia, pẹlu àwọn tí ó ń képe Oluwa pẹlu ọkàn mímọ́.

Timoti Keji 2

Timoti Keji 2:18-26