Timoti Keji 1:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí nìyí tí mo fi ń rán ọ létí pé kí o máa rú ẹ̀bùn-ọ̀fẹ́ Ọlọrun sókè, tí a fi fún ọ nípa ọwọ́ mi tí mo gbé lé ọ lórí.

Timoti Keji 1

Timoti Keji 1:2-14