Timoti Keji 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ranti igbagbọ rẹ tí kò lẹ́tàn, tí ó kọ́kọ́ wà ninu Loisi ìyá-ìyá rẹ, ati ninu Yunisi ìyá rẹ, tí ó sì dá mi lójú pé ó wà ninu ìwọ náà.

Timoti Keji 1

Timoti Keji 1:1-12