Tẹsalonika Kinni 5:17-19 BIBELI MIMỌ (BM)

17. Ẹ máa gbadura láì sinmi.

18. Ẹ máa dúpẹ́ ninu ohun gbogbo nítorí èyí ni ìfẹ́ Ọlọrun nípa Kristi Jesu fun yín.

19. Ẹ má máa da omi tútù sí àwọn tí ó ní ẹ̀bùn Ẹ̀mí Mímọ́ lọ́kàn.

Tẹsalonika Kinni 5